sentence
stringlengths
21
391
Iléẹjọ́ ní kí Dáre gé oko àgọ́ ọlọ́pàá fọ́jọ́ méjì.
Gbajúmọ̀ olukọ ni Fẹmi Ọlọ́runníṣọla lásìkò ogun jálumi
Ọmọ kan káwọ́ sẹ́yìn rojọ́ lórí ẹ̀sùn láti gbẹ̀mí ìyá rẹ̀.
Èyí ni àwọn ìpa tó yẹ kí ìjọba kọ́ lórí ìlọsíwájú àwọn ọ̀dọ́.
Adéwálé Ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ ní àìkàwé ló ṣàkóbá fún òun nínú iṣẹ́ tíátà.
Mímikò ti padà sí ẹgbẹ́ rẹ̀ àtijọ́ lẹ́yìn ìpàdé ìdákọ́ńkọ́
Àjọ tó ń mójútó ètò ìdìbò nílẹ̀ yí ti ṣe àkójọpọ̀ orúkọ ọdún yìí
Ẹ̀kọ́ márùn-ún tí wà láti dẹ́kun àjàkálẹ̀ ààrùn.
Àwọn òṣìṣẹ́ padà sí ẹnu iṣẹ́ ní ìpińlẹ̀ Ọ̀ṣun.
Àwọn obìnrin dáwó ra ọkọ̀ láti máa fi gbé aláboyún.
Iṣẹ́ yíyàwòrán ti di iṣẹ́ tí gbogbo ọ̀dọ́ fẹ́ ṣe.
Ìgbòho ké sáwọn olólùfẹ́ rẹ̀ láti dáríji agbẹjọ́rò rẹ̀.
Obìnrin tó ló ìwé kíkọ́ láti tọ́ ara rẹ ti di olówó báyìí
Ẹ̀sùn ìpànìyàn ti wọ́pọ̀ jù ní ìlú Ìbàdàn.
Bọ̀dé sọ pé ẹ̀ẹ̀kan péré ni òun bá ẹgbẹ́ òṣèlú òun ṣeré papọ̀
Tinubu ṣe iṣẹ́ abẹ nílùú òyìnbó.
Adé ṣàlàyé bó ṣe di agbẹjọ́rò fún Bàbá Ìjẹ̀sà.
Wọ́n fárígá pé ẹ̀tàn ló fi ń ṣe ìjọba rẹ̀.
Àṣírí ọ̀nà àbáyọ sí gbogbo ọ̀rọ̀ Nàìjíríà ni ká máa gbàdúrà.
Èyí ni ètò ìsìnkú Aàrẹ ìlú Òkè Ọya kan tó kú lánàá
Àjọ aṣóbodè ti kìlọ̀ fún àwọn ilé iṣẹ́ ìjọba láti dẹ́kun ríra ọkọ̀ tòkunbọ̀
Ó ní ọwọ́ àwọn ológun ló lè ká rògbòdìnyàn tó ń lọ lọ́wọ́.
Àkànbí dèrò ọ̀run nítorí 'Eré orí ẹní' ní ìlú Èkó
Àìgbọ́raẹniyé ló wáyé láàrín Bọ́lá ài igbákejì ẹ̀ lọ́jọ́ náà
Ìjọba àpapọ̀ ní ẹjọ́ láti jẹ lórí ìpànìyàn náà.
Adé gbàlejò akọ̀wé Amẹ́ríkà lánàá.
Àdúrà ni orílẹ̀-èdè yìí nílò.
Kò sí ẹni tó ní kí ń má wá sí Èkó.
Wo àkọsílẹ̀ nípa ìtan ayé àwọn oludìbò gómìnà Ọ̀yọ́.
Akọrin ẹ̀mí ní àánú Ọlọ́run ló sọ òun di akọrin.
Ayé ni Adẹ́mọ́lá fẹ́ jẹ kí n tó sọ̀rọ̀ ọ̀run.
Ẹnikẹ́ni tó bá gbélé fún ọmọ oníjìbìtì ma ṣẹ̀wọ̀n.
Adébánjo ní àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin gbọdọ̀ darapọ̀ mọ́ ìjọba.
Mo bẹ Àdùnní kó bá mi se ọbẹ̀ tí màá fi jẹun.
Ṣé òótọ ni pé ènìyàn leè kó ààrùn olóde láti ara bàtà?
Agbẹjọ́rò ní kò sí àrídájú pé Ìgbòho ló ni ilé tí ìjọba kọlù.
Ìró ìbọn yìí dún gbàù lásìkò ìpàdé àwọ ọmọlẹ́yìn Arẹ́gbẹ́ṣọlá
Ọlọ́pàá ní àwọn ti mú afunrasí kan tó mọ̀ nípa ikú Bísọ́lá
Àgùnbánirọ̀ sọ pé omi àti iyẹ̀pẹ̀ ni sọ́jà fi bá òun jà
Èdè aìyedè wà lórí bí ẹ̀gbọ́n ìyàwó Bukola ṣe kú ní Èkó.
Ìlànà Ọmọ Yorùbá ṣe pàtàkì fún wa.
Mo nífẹ̀ẹ́ sí kin máa mu Gàrí ní Nàìjíríà ju ìlú mi lọ.
Adé jáde láyé lẹ́ni ọmọ ogún ọdún.
Àrùn ọpọlọ ń da ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn láàmú ní ilé Adébọ̀wálé
Owó púpọ̀ ni màmá náà nílò láti ṣòwò jèrè lọ́jà.
Ọ̀pọ àwọn akékọ̀ọ́ ti wá nnkan mìíràn ṣe nínú ìyanṣélódì.
Àwọn ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Òǹdó ṣì ń tẹ̀síwájú nínú ìwádìí wọn.
Ibi tí àwọn nọ́ọ̀sí ti ń ṣiṣẹ́ kò pójú òṣùwọ̀n rárá.
Àjọ tó ń rísí ìtọ́jú àwọn ará ìlú ti kéde ènìyàn méji tó kú.
Ìyàwó mi fi mí sílẹ̀ kó lọ sílé ọkùnrin míì nínú báráàkì kan náà.
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rìnlà ló pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìjàm̀bá
Oluwapọ̀nmile sọ ìrírí rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn sójà tó fìyàjẹ́ ní Ibadan.
Ọmọ náà ló máa n fa àwọn ìjà kéékèèké láàárín ìyá àti bàbá rẹ̀
Ohun méta rèé tó máa ń fa kí orí máa fọ́ ènìyàn
Gómìnà Akérédolú la Jégédé mọ́lẹ̀ wọlé ìbò gómìnà Òǹdó.
Àbáyọ̀mí ti rọ àwọn ọ̀dọ́ láti ṣọ́ra, ki wọ́n má baà di ẹran àmúso
Ààrẹ ìlú kan ní Áfíríkà ṣ'èdárò Ẹja akóredé tó papòdà.
Arẹ́gbẹ́ṣọlá sọ pé àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ ló máà ń mu ọtí jù
Ọmọ títọ́ kìí ṣe tí àwọn òbí nìkan, gbogbo àwùjọ ló ń tọ ọmọ.
Iléeṣẹ ọlọpàá mú Adé lorí pé o fipá bá akẹkọọ lò pọ.
Ìran Yorùbá kìí ṣe ọ̀lẹ tàbí olè rárá.
Mo gbàdúrà kí Ọlọ́run tu gbogbo ẹbí wa nínú.
Dáramọ́la Abíọ́dún tó jé agbenusọ fún ìjọba ló ṣẹ̀ṣẹ̀ dé
Ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àwọn kò tíì gbọ́ nípa ikú aṣòfin ìpínlẹ̀ Eko to kú
Ta ló tún fé bá mi ní ìbálòpọ̀ọ̀ báyìí?
Àwọn jàǹdùkú kan ti ń dúnkookò mọ ọrọ̀ ajé àwọn ọlọ́jà.
Ìdìtẹ̀gbàjọba gbàjọba ti ṣẹlẹ̀ láìmọye ìgbà nílè Nàíjíríà.
Ọba Gbọ́láhàn Shómólú ti jẹ́wọ́ pé àṣìṣe ni òun ṣe.
Ọ̀pọ̀ ọ̀gá òṣèré ló ń bèèrè ìbálòpọ̀ lọ́wọ́ àwọn ègbè lẹ́yìn wọn
Àwọn òṣìṣẹ́ kólẹ̀-kódọ̀tí ń fi ẹ̀mí wọn wéwu ní ìlú Èkó.
Agbẹjọ́rò Báyọ̀ ní ìbanilórúkọjẹ́ ní wọ́n fí ẹ̀sùn gbájúẹ̀ ṣe.
Ìpolongo ìdíje sípò gómínà ti gbéraṣo ní ìlú Ọ̀ṣun.
Ọ̀gá ọlọ́pàá pàṣẹ pé kí wọ́n ṣé ìwádìí lórí ọlọ́pàá inú àwòrán.
Àwọn aláṣẹ kejì yìí ló ṣàlàyé bí ìbọn ṣe bá akẹ́kọ̀ọ́ àkọ́kọ́
Gómìnà ìlú Èkìtì fi ipò kejì dá Sànúsí lọlá láàárín ọjọ́ méjì.
Adépọ̀jù ti dé iwájú adájọ́ méjì kó tó rí àánú gbà
Simi àti ọkọ ẹ̀ ti darí sí ìlú òyìnbó láti pàdé àwọn ẹbí wọn
Ẹ wo báwọn ọmọ ọ̀ṣọtà ṣe ya bó màmá Ire.
Akérédelú ní Bọ́lá kájúẹ̀ láti ṣe àkóso Nàíjíríà.
Títí di ìparí oṣù kẹwàá ni a ó gba ìwé-àṣẹ ìwakọ̀
Dókítà Àlàní ti kó àrùn tí kò gbọ́ òògùn.
N kò gba kọ́bọ̀ lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni láti wá náà ọ̀daràn jáde.
Àǹfààní márùn-ún ló wá nínú ìmọ̀ nípa ìṣòwò lọ́ja Ayẹ́yẹ́
Wọ́n yìbọn sókè káàkiri nínú agbègbè Gbági, mo sì sá lọ.
Owó oúnjẹ ni mo lọ ọ gbà lọ́wọ́ bàbá mi.
Yorùbá béèrè kókó ǹkan mẹ́fà lọ́wọ́ Adẹ́mọ́lá.
Ẹniọlá Adékúnlé ti gbé fọ́tò bàbá ẹ̀ sálọ sínú igbó
Mo gbọ pé ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin júwe ilé fáwọn alága ìjọba ìbílẹ̀
Yínká fún Ìkẹ́olúwa ní oyún lẹ́yìn ọdún méjì tí wón ti wà.
Àwọn ọlọ́pàá kan ti pàdé Babájídé láti bèère oun tí wọ́n fẹ́
Olóyè Ayọ̀ ti ń bèèrè ìtúsílẹ̀ àwọn tí wọ́n jí gbé báyìí
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti fòpin sí ìyanṣẹ́lódì ọlọ́jọ́ mẹ́rin wọn
Kúnlé fẹ́ràn iyan àti ẹran ìgbẹ́.
Màmá Sọjí ti di asojú ilé iṣẹ́ kan nílẹ̀ òkèrè.
Ilé ẹjọ́ dá arákùnrin náà dúró láti gbé ọmọ ógún ọdún sílé.
Ọmọ ilé ẹ̀kọ́ wa méjì fórí kó ọta ìbọn lọ́jọ́ kan ṣoṣo.
Ojú àwọn ará Èkó rí màbo pẹ̀lú òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá tó bẹ́ sílẹ̀.
Ọbásanjọ́ ti kọ̀ nítorí wàhálà tó ń wáyé lẹ́gbẹ́ òṣèlú rẹ̀
Èmi kọ́ ló gbé orin ọdún ń lọ sópin kalẹ̀.
Kokoko lara mí le, Mo kàn ń gbà ìtọ́jú nílé ìwòsàn ni